WAEC Yoruba 2024 · try it first
Táyé: E mà kú ojó méta kan. Adéolá: Àwa mà niyen o Táyé: E şáà kú owó lómi iyá Kúnbi, ègbón rẹ (Oláidé, ore won, dé bá wọn lórí idúró) Oláídé: a bárikà omọ tuntun o, Olórun á wò ó. Adéolá: Adùn á kárí o. Táyé: Báwo wá ni ètò isomolórúko? Adéolá: Bí àwon bàbá wa ti í şe é náà ni. À bó o ti gbàgbé? Omokùnrin, ojó mésàn-án, Omobinrin, ojó méje, ti ti ibeji jé ojó méjo. Oláidé: Ę şáà féé se é bí wón ti íşe é, kí ó baà rí bí ó ti máa ń rí. Adéolá: Okùnrin kan, obìnrin kan kúkú ni àwon omọ náà. Mo tilè gbó pé èyí okùnrin dojú bolė, èyí obinrin gbé ibi kórùn. Táyé: Ha! Ajàyí àti Ainá niyen. Adéolá: Abósèdé tíó jé àbikéyìn iyá wa ti lọ ra àwọn ohun-èlò isomolórúko bíi irèké, oyin, àádùn, obi, orógbó àti ataare ní ojà oba. Oláidé: Á jé pé kí obi bikú dànù, kí orógbó gbó wọn sáyé. Adéolá: Âşę o, a ó tún máa ríra lójó méfà òní. a ni ó dé bá Táyé àti Adéolá níbi tí wón ti ń sor? sáyé.