WAEC Yoruba 2025 · try it first
Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe. Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn. Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn. Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé. Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện. Àwọ̀ wo ni a pọ̀ pọ̀ láti ṣe àwọ̀ òfèéfèé?