WAEC Yoruba 2024 · try it first
Aago márùn-ún idájí ni Şeun ti jí jáde nilé lo wO Okò tíóńlo sí idànrè. Ibùdókò Qjóta ni ó lo kí6 tètè rí okò wò. aago méwàá ni okò tó kún. Ki wón tó dễ Sàgámù ni ọkò ti bèrè sí yọnu. Agbára káká ni Nón fì dé ilé-işé atókòşe kan lébàá Ôgbolú. Kí wón tó ri okò şe tán, aago mérin iròlé ti lù. Géré tí wón dể sebú-Òde ni okò bá tún dẹnu kolè. Ojú ojó ti ń po firi, aago méje ti férèé lù kí wón tỏó dé Orè níbi tí awakò ti so pé òun ò lè lo mó. Seun wá gbà pé òun ti şi rin ní ojó náà. ojó tí kò níí gbàgbé láéláé ni ojó náà jé fún un. Ó ronú eni i òun kókó jí rí ní ojó yi, kò rántí; ó féé mọ bí yóò şe yera fún onítòhún.Ó tó wákàtí kan tíó ti ń wá okò niíràn tí kò rí. Lóji ni òjò bèrè síf rò. Òjò òhún kò tilệ I Abé orùlé ni ó sá sí títí di aago mésàn-án àb ki wón tóó rí okò tí ó kó méta nínú won lo. Déédéé aago méjilá àbò òru ni ó tó wo İdànrè ní ojó tí à ń wi yi. Bí aago mélòó ni awakò tóó so pé òun kò le lo mó?