WAEC Yoruba 2016 · try it first
Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé òkóókan won. Omo bibí lú Béyiòşe ni İşòlá. Òun àti àbúrò rè, Foláhànmí, nikan ni Bádéjo, bàbá wọn bí. Agbè onikòkó aládàáńlá ni Bádéjo. Bólátitó, aya rè, sì jé oníşòwò obi. Bádėjo kò kàwé şùgbón ó pinnu láti tó àwọn omo rè méjèèji débi tí wón bá lè kàwẻ dé láyé, nítorí pé iyà àikàwé je é púpò nídií òwò tí ó ń şe. Léyin ti İşolá parí iwé méwàá ní ilú ibòdi ni ó gba ilú Arómisá lo láti tè síwájú nínú èkó rè ní fásiti. ilú ọba ni ó si ti gba oyè imó ijinlè keji nínú òfin. İşòlá padà sí ilú Bėyiòşe, ở si di gbajúgbajà agbęjórò kájkiri agbègbè náà. Ilú abinibi Bådéjo ni ?