WAEC Yoruba 2025 · try it first
Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee. Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó. Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba. Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú. Èwo ni èyìn rẹ ní sán-án-yán lára?